QDOT – Ole

 

Qdot-Ole

Asiko ti to, refree ti blow final whistle po po po
Po po po po ro
Don’t f*** with my generation oooo
Qdot l’orukọ mi
Ominira lo pada di omi ti o ni wa lara
lya yi ti’n jọ awọn baba wa tipẹ wọn fura
Wọn fi oju commonnize
O tẹ wọn lọrun ko gba rice
Kon ṣe pe naija ko tẹ wan lọrun
Ti ijọba fẹ fi okun si wa lọrun – America, Canada visa wa da bi visa ijọba ọrun (Mo gbe)
Ọrọ wa ti wa ni BBC, my brother get your PVC
Ẹ ba’n kigbe ole o (ole)
Ajibole (ole)
A gbọ yin lẹyin (ole)
Ẹ dakun ẹ sọrọ soke (ole)
Ẹ ba’n kigbe ole (ole)
Ajibole (ole)
Ẹ ba’n kigbe ole (ole)
Ole ajibole (ole)

Snake come, e chop
Monkey come, e chop
Office don they burn
our money is gone
I they hear 40 billion, 90 billion gbogbo ẹ ṣa Ion billi billi
Ka to ṣẹju wọn ti na firi firi
lya pikin they chop pizza, poor man they chop lizard
Wọn ni ẹ end SARS eyi si SWAT ẹ ma pa mi be ṣe pa Kọlade
Ẹ ba’n kigbe ole o (ole)
Ajibole (ole)
A gbọ yin lẹyin (ole)
Ẹ dakun e soro soke (ole)
Ẹ ba’n kigbe ole (ole)
Ajibole (ole)
Ẹ ba’n kigbe ole (ole)
Ole ajibole ole (ole)

Ẹ ba’n kigbe (ole o)
Tẹ ba ti won e da won mo
Wọn na owo yafun yafun
Wọn ra moto fafun fafun, Ole ni wọn
Ogara ọlọṣa ni wọn
Tẹ ba ri wọn ẹ da wọn mọ
Ẹ sọrọ soke
Ọkẹrẹ ti k’oju ija si ọlọdẹ